Mika 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ dìde, ẹ máa lọ, nítorí pé ìhín yìí kì í ṣe ibi ìsinmi; nítorí pé ẹ ti hùwà ìríra tí ń mú ìparun ńlá báni.

Mika 2

Mika 2:7-13