Mika 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé egbò Samaria kò lè ṣe é wò jinná; egbò náà sì ti ran Juda, ó ti dé ẹnubodè àwọn eniyan mi, àní, Jerusalẹmu.”

Mika 1

Mika 1:6-15