Mika 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará Mareṣa, n óo tún jẹ́ kí àwọn ọ̀tá borí yín; ògo Israẹli yóo sì lọ sí ọ̀dọ̀ Adulamu.

Mika 1

Mika 1:9-16