Matiu 9:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí ó ti lé àwọn eniyan jáde, ó wọ inú ilé, ó mú ọmọbinrin náà lọ́wọ́, ọmọbinrin náà bá dìde.

Matiu 9

Matiu 9:15-34