Matiu 9:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá yipada, ó rí obinrin náà, ó ní, “Ṣe ara gírí, ọmọbinrin. Igbagbọ rẹ ti mú ọ lára dá.” Ara obinrin náà bá dá láti àkókò náà lọ.

Matiu 9

Matiu 9:12-25