Matiu 8:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ìlú bá jáde lọ pàdé Jesu. Nígbà tí wọ́n rí i, wọ́n bẹ̀ ẹ́ pé kí ó jọ̀wọ́ kí ó kúrò ní agbègbè wọn.

Matiu 8

Matiu 8:32-34