Matiu 8:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá kígbe pé, “Kí ni ó pa tàwa-tìrẹ pọ̀, ìwọ Ọmọ Ọlọrun? Ṣé o dé láti wá dà wá láàmú ṣáájú àkókò wa ni?”

Matiu 8

Matiu 8:24-31