Matiu 8:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnu ya àwọn eniyan náà. Wọ́n ní, “Irú eniyan wo ni èyí, tí afẹ́fẹ́ ati òkun ń gbọ́ràn sí i lẹ́nu?”

Matiu 8

Matiu 8:19-34