Matiu 8:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìgbì líle kan sì dé lójú omi òkun; ó pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ó jẹ́ pé omi fẹ́rẹ̀ bo ọkọ̀; ṣugbọn Jesu sùnlọ.

Matiu 8

Matiu 8:21-27