Matiu 8:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnìkan tí ó ní àrùn ẹ̀tẹ̀ sì wá, ó kúnlẹ̀ níwájú rẹ̀, ó ní, “Alàgbà bí o bá fẹ́, o lè sọ ara mi di mímọ́.”

Matiu 8

Matiu 8:1-8