Matiu 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá fi ọwọ́ kàn án lọ́wọ́, ibà náà sì fi í sílẹ̀. Ó bá dìde, ó bá tọ́jú oúnjẹ fún un.

Matiu 8

Matiu 8:6-19