Jesu bá sọ fún ọ̀gágun náà pé, “Máa lọ, gẹ́gẹ́ bí o ti gbàgbọ́, bẹ́ẹ̀ ni kí ó rí fún ọ.”Ara ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ̀ sì dá ní àkókò náà gan-an.