Matiu 7:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Òjò rọ̀, àgbàrá dé, ẹ̀fúùfù sì kọlu ilé náà. Ó bá wó! Wíwó rẹ̀ sì bani lẹ́rù lọpọlọpọ.”

Matiu 7

Matiu 7:17-29