Matiu 7:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ gan-an ni: gbogbo igi tí ó bá dára a máa so èso tí ó dára; igi tí kò bá dára a máa so èso burúkú.

Matiu 7

Matiu 7:9-25