Matiu 6:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹ kọ́kọ́ máa wá ìjọba Ọlọrun ná ati òdodo rẹ̀, gbogbo nǹkan wọnyi ni a óo fi kún un fún yín.

Matiu 6

Matiu 6:32-34