Matiu 6:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹ mo sọ fun yín pé Solomoni pàápàá ninu gbogbo ìgúnwà rẹ̀ kò lè wọ aṣọ tí ó lẹ́wà bíi ti ọ̀kan ninu àwọn òdòdó yìí.

Matiu 6

Matiu 6:22-34