Matiu 6:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ojú ni ìmọ́lẹ̀ ara. Bí ojú rẹ bá ríran kedere, gbogbo ara rẹ yóo ní ìmọ́lẹ̀.

Matiu 6

Matiu 6:12-23