Matiu 6:14 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí bí ẹ bá dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn eniyan jì wọ́n, Baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run yóo dáríjì yín.

Matiu 6

Matiu 6:4-19