Matiu 5:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Tí ẹ bá ń kí àwọn arakunrin yín nìkan, kí ni ẹ ṣe ju àwọn ẹlòmíràn lọ? Mo ṣebí àwọn abọ̀rìṣà náà ń ṣe bẹ́ẹ̀!

Matiu 5

Matiu 5:46-48