Matiu 5:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó bá bèèrè nǹkan lọ́wọ́ rẹ, fi fún un. Má ṣe kọ̀ fún ẹni tí ó bá fẹ́ yá nǹkan lọ́wọ́ rẹ.

Matiu 5

Matiu 5:32-43