Matiu 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni adánniwò bá yọ sí i, ó sọ fún un pé, “Bí Ọmọ Ọlọrun bá ni ọ́ nítòótọ́, sọ fún àwọn òkúta wọnyi kí wọ́n di àkàrà.”

Matiu 4

Matiu 4:1-5