Matiu 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Èṣù fi í sílẹ̀. Àwọn angẹli bá wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n ń ṣe iranṣẹ fún un.

Matiu 4

Matiu 4:9-12