Matiu 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Jesu lọ láti ilẹ̀ Galili, sọ́dọ̀ Johanu ní odò Jọdani, kí Johanu lè ṣe ìrìbọmi fún un.

Matiu 3

Matiu 3:12-17