Matiu 28:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ mì tìtì, nítorí angẹli Oluwa sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run wá. Ó yí òkúta tí ó wà lẹ́nu ibojì kúrò, ó sì jókòó lórí rẹ̀.

Matiu 28

Matiu 28:1-7