Matiu 27:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí wọ́n ti forí-korí, wọ́n fi owó náà ra ilẹ̀ amọ̀kòkò fún ìsìnkú àwọn àlejò.

Matiu 27

Matiu 27:1-11