Matiu 27:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n jáde kúrò ninu ibojì lẹ́yìn tí Jesu ti jí dìde, wọ́n wọ Jerusalẹmu lọ, ọpọlọpọ eniyan ni ó rí wọn.

Matiu 27

Matiu 27:48-59