Matiu 27:49 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn yòókù ń sọ pé, “Fi í sílẹ̀! Jẹ́ kí a wò bí Elija yóo wá gbà á là.”

Matiu 27

Matiu 27:41-54