Matiu 27:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn Juu pésẹ̀, Pilatu bi wọ́n pé, “Ta ni kí n dá sílẹ̀ fun yín, Jesu Baraba ni tabi Jesu tí ó ń jẹ́ Mesaya?”

Matiu 27

Matiu 27:9-18