Matiu 27:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí àṣà, ní àkókò àjọ̀dún, gomina a máa dá ẹlẹ́wọ̀n kan sílẹ̀ fún àwọn eniyan, ẹnikẹ́ni tí wọn bá fẹ́.

Matiu 27

Matiu 27:12-18