Matiu 26:69 BIBELI MIMỌ (BM)

Peteru jókòó lóde ní àgbàlá. Ọ̀kan ninu àwọn iranṣẹbinrin wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ó ní, “Ìwọ náà wà pẹlu Jesu ará Galili.”

Matiu 26

Matiu 26:66-73