Matiu 26:57 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n mú Jesu fà á lọ sọ́dọ̀ Kayafa Olórí Alufaa, níbi tí àwọn amòfin ati àwọn àgbà ti pé jọ sí.

Matiu 26

Matiu 26:47-62