Matiu 26:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Tabi o kò mọ̀ pé mo lè ké pe Baba mi, kí ó fún mi ní ẹgbaagbeje angẹli nisinsinyii?

Matiu 26

Matiu 26:45-58