Matiu 26:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wí fún un pé, “Mo fẹ́ kí o mọ̀ dájúdájú pé ní alẹ́ yìí, kí àkùkọ tó kọ, ìwọ yóo sẹ́ mi ní ẹẹmẹta.”

Matiu 26

Matiu 26:28-44