Matiu 26:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí ni ẹ̀jẹ̀ mi tí a fi dá majẹmu, ẹ̀jẹ̀ tí a ta sílẹ̀ fún ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ ọpọlọpọ eniyan.

Matiu 26

Matiu 26:18-30