Matiu 26:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Judasi, ẹni tí ó fi í fún àwọn ọ̀tá, bi í pé, “Àbí èmi ni, Olùkọ́ni?”Jesu dá a lóhùn pé, “O ti fi ẹnu ara rẹ sọ ọ́.”

Matiu 26

Matiu 26:20-27