Matiu 25:31 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí Ọmọ-Eniyan bá yọ ninu ìgúnwà rẹ̀ pẹlu gbogbo àwọn angẹli, nígbà náà ni yóo jókòó lórí ìtẹ́ ògo rẹ̀.

Matiu 25

Matiu 25:25-34