Matiu 25:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bẹ́ẹ̀ náà ni ẹni tí ó gba àpò meji wá, ó ní ‘Alàgbà, àpò meji ni o fún mi. Mo ti jèrè àpò meji lórí rẹ̀!’

Matiu 25

Matiu 25:20-32