Matiu 25:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kíá, bí ó ti lọ tán, ẹni tí ó gba àpò marun-un lọ ṣòwò, ó bá jèrè àpò marun-un.

Matiu 25

Matiu 25:12-22