Matiu 24:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí orílẹ̀-èdè yóo dìde sí orílẹ̀-èdè; ìjọba yóo dìde sí ìjọba. Ìyàn yóo mú. Ilẹ̀ yóo máa mì ní ọpọlọpọ ìlú.

Matiu 24

Matiu 24:1-10