Matiu 24:51 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀gá rẹ̀ yóo wá nà án, yóo fi í sí ààrin àwọn alaiṣootọ. Níbẹ̀ ni yóo máa gbé sunkún tí yóo sì máa payínkeke.

Matiu 24

Matiu 24:42-51