Matiu 23:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn á di ẹrù wúwo, wọn á gbé e ka àwọn eniyan lórí, bẹ́ẹ̀ ni àwọn fúnra wọn kò sì jẹ́ fi ọwọ́ wọn kan ẹrù náà.

Matiu 23

Matiu 23:1-8