Matiu 23:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ gan-an ni ẹ̀yin náà rí lóde, lójú àwọn eniyan ẹ dàbí ẹni rere, ṣugbọn ẹ kún fún àṣehàn ati ìwà burúkú.

Matiu 23

Matiu 23:23-38