Matiu 23:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin afọ́jú òmùgọ̀ wọnyi! Èwo ni ó ṣe pataki jù! Wúrà ni tabi Tẹmpili tí a fi sọ wúrà di ohun ìyàsọ́tọ̀?

Matiu 23

Matiu 23:13-19