Matiu 22:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dá a lóhùn pé, “ ‘Fẹ́ Oluwa Ọlọrun rẹ pẹlu gbogbo ọkàn rẹ, ati gbogbo ẹ̀mí rẹ, ati ní gbogbo èrò rẹ.’

Matiu 22

Matiu 22:29-39