Matiu 22:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ní àkókò ajinde kò ní sí pé à ń gbé iyawo, tabi pé à ń fi ọmọ fún ọkọ; nítorí bí àwọn angẹli ti rí ní ọ̀run ni wọn yóo rí.

Matiu 22

Matiu 22:25-35