Matiu 22:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Tí ó bá di àkókò ajinde, ninu àwọn mejeeje, iyawo ta ni obinrin náà yóo jẹ́, nígbà tí ó jẹ́ pé gbogbo wọn ni wọ́n ti fi ṣe aya?”

Matiu 22

Matiu 22:18-30