Matiu 22:24 BIBELI MIMỌ (BM)

“Olùkọ́ni, Mose sọ pé bí ẹnìkan bá kú láì ní ọmọ, kí àbúrò rẹ̀ fẹ́ aya rẹ̀ kí ó lè bí ọmọ fún ẹ̀gbọ́n rẹ̀.

Matiu 22

Matiu 22:17-32