Matiu 22:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dá a lóhùn pé, “Ti Kesari ni.”Ó bá sọ fún wọn pé, “Tí ó bá rí bẹ́ẹ̀, ẹ fi ohun tí ó jẹ́ ti Kesari fún Kesari, kí ẹ sì fi ohun tíí ṣe ti Ọlọrun fún Ọlọrun.”

Matiu 22

Matiu 22:14-23