Matiu 22:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jesu mọ èrò ibi tí ó wà lọ́kàn wọn. Ó ní, “Kí ló dé tí ẹ fi ń dẹ mí ẹ̀yin alárèékérekè yìí?

Matiu 22

Matiu 22:10-20