Matiu 22:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bi í pé, ‘Arakunrin, báwo ni o ti ṣe wọ ìhín láì ní aṣọ igbeyawo?’ Ṣugbọn kẹ́kẹ́ pamọ́ ọkunrin náà lẹ́nu.

Matiu 22

Matiu 22:4-20